Discuss Scratch

LearningKid3
Scratcher
42 posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

se o n wa iroyin titun fun ede Yoruba?

Last edited by LearningKid3 (April 7, 2025 00:59:57)

LearningKid3
Scratcher
42 posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

awa nilo se studio Yoruba nibo awon eniyan Yoruba maa wa lati jiroro ati so pelu awon miiran ni ede Yoruba.

Last edited by LearningKid3 (April 15, 2025 15:03:41)

LearningKid3
Scratcher
42 posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

beni, awa nilo se kankan, hey mo fe bere ibere, se e ti mo pe, ni Lagos, Yoruba je dandan nissi, won lo Yoruba ni awon plenaries ose kookan ati ni Osun paapaa. Sugbon, Yoruba ko wa dandan ni ipinle Oyo, sugbon won lo Yoruba ni plenaries ose kookan, inu mi dun gidigidi, ile Yoruba gbiyanju lati fipamo ede Yoruba, hooray!!
LearningKid3
Scratcher
42 posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

won ti se itumo fun awon iwe imo-jinle ni ede Yoruba! O dara gidigan oh!
ti e ba so ede ti okunrin ye, o ma gbo o, sugbon ti e ba so ede okunrin, o ma duro ninu okan re.

Last edited by LearningKid3 (April 16, 2025 03:57:50)

veggietherian
Scratcher
1 post

The Yoruba language (Ede Yoruba)

gbolohun laileto ni ede yoruba
LearningKid3
Scratcher
42 posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

E pele, sugbon awon aworan, won ko sise lori yii

Last edited by LearningKid3 (April 16, 2025 23:39:43)

acohen_bhusd
Scratcher
500+ posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

shouldn't the translation be done
acohen_bhusd
Scratcher
500+ posts

The Yoruba language (Ede Yoruba)

bump

Powered by DjangoBB